Ekaabo si ijo Emmanuel
A je ijo igbalode ati ijo Kiristiani to gbagbo ninu Bibeli. A ma n pade ni ilu Durham ati Chester-le Street. A fe je ijo to o dagba soke ati ijo fun gbogbo ebi ti o wo gbogbo agbalaya aiye.
A fe ni ilo siwaju a sife idagba si ninu ise Olorun. Bi a seje ile olorun fun gbogbo ebi, ilekun wa si si fun gbogbo eyan. A ma n ki gbogbo eniyan kaabo bi ebi wa. A fe ko ile olorun pelu awon ebun ti Olorun fi fun wa asi fe fi ayo wa han ni orisirisi ona. A wa ni ilu Durham a si n wo awon ilu miran bi South Africa ati India.
A ma n pade bi ijo ni ojo Aiku ni agogo mewa abo. Awon Ijo kekere na ma n pade kakiri ilu Durham. Ninu awon ijo kekere yi, a ye wa fun ibasepo ore ati igbani ni iyanju. A ni aye itoju fun awon omode ati awon odo nigbati a ba pade ni ojo Aiku ati larin ose.
A je ara awon igbimo ijo Region Beyond. Awon eyan lati orilede gbogbo ma n darapo mo wa. A wa na ma n ran awon eyan lo si awon orile ede miran. A ma nife lati pade yin fun nkan mimu ni ojo Aiku kato bere isin ni ago mewa tabi leyin isin na.